Afárá já sódò lẹyìn tí ọkọ̀ ojú omi kọlùú ní Brazil

Ọkọ oju omi agbero ‘fẹri’ kan ti kọlu afara kan nipinlẹ Pará lagbegbe ariwa orileede Brazil. Ikọlu yi mu ki apa kan afara naa dawo sinu odo ti o gba ori rẹ kọja eleyi ti wọn pe orukọ rẹ ni…

Aliko Dangote: Mo gbà $10m ní bánkì kí o lè dami loju pé lòótọ́ ní mò lowo

Olokoowo to lowo ju lọ ni Afrika Aliko Dangote ti ṣọ bi ohun ti ṣe gba miliọnu dọla mẹwa ni banki tori pe ohun fẹ mọ daju pe lootọ ni ohun lowo to to bẹ. Nibi apero Mo Ibrahim to…

Kolade Johnson: Adájọ́ pàṣẹ kí wọ́n fi ọlọ́pàá tó lọ́wọ́ nínú ikú Kolade Johnson sí àhámọ́

Inspẹkitọ ọlọpaa ti wọn yọ niṣẹ lori ọrọ arakunrin Kolade Johnson ti wọn yinbọn pa nilu Eko ti foju ba ile ẹjọ. Adajo paṣẹ bakannaa pe ki wọn lọ fi si ahamọ titi di igba ti wọn yoo fi gbẹjọ…

EXCLUSIVE: Onnoghen resigns as CJN ‘with immediate effect’

Walter Onnoghen has resigned as the chief justice of Nigeria (CJN) with immediate effect, TheCable can report. He turned in his resignation letter to President Muhammadu Buhari on Thursday evening, a day after the National Judicial Council (NJC) recommended that he…

Pan-Yoruba group, ARG, calls for full electronic voting in 2023

A Yoruba socio-political group, Afenifere Renewal Group (ARG), on Sunday advocated implementation of electronic voting in the country before the next general elections. It also asked that current voters register be cleaned up before contemplating conduct of the next elections.…

Yoruba will no longer play second class fiddle in Nigeria – Ooni of Ife, Fayemi’s CoS

The Ooni of Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi and the Chief of Staff to Ekiti state governor, Mr Biodun Omoleye, have said the southwest region won’t play a second fiddle again in the politics of the nation. They said in…

Àwọn wo ló kó oníkẹ̀ẹ̀kẹ́ ‘Napep’ wọ ìgboro ìlú Liverpool?

Bi ẹ ba laanfaani lati lọ si ilu ọba, ẹ ri wi pe ẹ foju sita boya ẹ o ṣe alabapade ‘Kẹẹkẹ Napep’ iru eleyi ti o n gbe ero lawọn ilu kaakiri Naijiria. Bẹẹni, ‘Kẹkẹ Napep’ ti n na…

Osun Tribunal Judgement: ‘Àwa ènìyàn Ọṣun kọ ìdájọ́ tó ní Oyetọla kọ́ ló wọlé sípò gómìnà’

Kẹtikẹti ni awọn olugbe ipinlẹ Ọṣun tu sita lọjọru lati ṣe iwọde tako idajọ igbimọ to sọ pe Sẹnetọ Ademọla Adeleke ti ẹgbẹ osẹlu Peoples Democratic Party lo jawe olubori ninu idibo sipo gomina ipinlẹ naa to waye lọdun 2018.…

Fashọla: Àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ lórí ìpèsè iná ọba tí mínísítà Fashọla ní ó ti ń ṣe dédé

Ṣe awọn agba bọ, wọn ni ẹyin lohun, bi o ba ti jabọ ko tun ṣee ko mọ. Lẹyin ti o ti sọrọ lori eto mohunmaworan abẹle kan lorilẹede Naijiria pe ọpọ ipinlẹ lorilẹede Naijiria ni wọn ti n ni…

Osun: Yoruba youths react to Adeleke’s victory

The Yoruba Council of Youths Worldwide (YCYW) has hailed the declaration of Sen. Adejola Adeleke, candidate of the Peoples Democratic Party (PDP) as winner of the Sept. 22, 2018 governorship election in Osun State. NAN quoted President of the youth…