Aisha Buhari: Ọkọ mi yóò parí gbogbo iṣẹ́ tó ti bẹ̀rẹ̀

Iyawo Aarẹ Orilẹede Naijiria, Aisha Buhari ti ni ọkọ oun yoo lo saa keji yii lati mu gbogbo ileri to ṣe lasiko ipolongo idibo lorilẹede Naijiria wa si imuṣẹ. Aisha Buhari lasiko to n gbalejo lati ṣayẹyẹ bi ọkọ rẹ…