Fashọla: Àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ lórí ìpèsè iná ọba tí mínísítà Fashọla ní ó ti ń ṣe dédé

Ṣe awọn agba bọ, wọn ni ẹyin lohun, bi o ba ti jabọ ko tun ṣee ko mọ. Lẹyin ti o ti sọrọ lori eto mohunmaworan abẹle kan lorilẹede Naijiria pe ọpọ ipinlẹ lorilẹede Naijiria ni wọn ti n ni…