Koffi Olomide: Ilé ẹjọ́ kan nílẹ̀ Faranse ló sọ́ sẹ́wọ̀n ọdún méjì

Koffi Olomidé, ọkan nínu àwọn gbajúgbàjajà olórin takansufe nìlẹ̀ Afíríkà, ní wọn ló jẹbi ẹ̀sùn pé ó fipá bá ọ̀kan lára àwọn ọmọ tó ń ba jó lopọ, nìgbà tí ò wà ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún. Bó tilẹ̀ jẹ pé…