Lagos: Àjọ iwádìí ọrọ̀ ajé àgbáyé, EIU ní Ilu eko wà lára àwọn ìlú tó gbọ̀pọ̀ jùlọ lagbaye

Njẹ ẹ mọ pe ipinlẹ Eko wa lara awọn ilu mẹwa ti owo gbigbe e rẹ gba ọpọ julọ lagbaye? Ajọ iwadi ijinlẹ nipa ọrọ aje lagbaye, Economist Intelligence Unit lo sọ bẹẹ ninu abajade iwadii ijinlẹ kan ti wọn…