Osun Tribunal Judgement: ‘Àwa ènìyàn Ọṣun kọ ìdájọ́ tó ní Oyetọla kọ́ ló wọlé sípò gómìnà’

Kẹtikẹti ni awọn olugbe ipinlẹ Ọṣun tu sita lọjọru lati ṣe iwọde tako idajọ igbimọ to sọ pe Sẹnetọ Ademọla Adeleke ti ẹgbẹ osẹlu Peoples Democratic Party lo jawe olubori ninu idibo sipo gomina ipinlẹ naa to waye lọdun 2018.…